COVID-19 ni eewu ilera fun gbogbo eniyan, ni pataki julọ ni awọn ti o wa ni aarọwọto bi awọn aṣikiri, awọn to nwa aabo ati asasala. Fun arun ti a ko ni iwosan tabi itọju ti a mọ fun, idaabobo ararẹ ati awọn omiiran kuro lọwọ COVID-19 ni o dara julọ. Oju-iwe yii nfunni ni […]

Wo gbogbo ẹ

Ti o ba jẹ aṣikiri tabi eniyan ti n wa aabo ni orilede omiran nigba ajakaye-arun COVID-19, oju-iwe yii ṣalaye bi o ṣe le wa alaye diẹ sii lori bi o ṣe le daabobo ararẹ ki o si wa l’alafia. FacebookTweetLinkedIn

Wo gbogbo ẹ

Ọpọlọpọ iró, ọrọ agbọ sọ ati alaye ti ko n ṣe ododo ni n kaakiri laarin awọn aṣikiri nipa COVID-19. Fun iranlọwọ lati le jẹ ki o gbe igbesẹ  ti o tona, a ti ṣe akojọpọ awọn iró ti o wọpọ julọ ki o ba le ni imọ lati daabobo ararẹ lakoko ajakaye-arun COVID-19. Fun […]

Wo gbogbo ẹ