Kan si wa

Oun rinrin ajo iṣilọ bi? Pe foonu wa fun imọran

Nje o ni ibeere lori irinajo lo si ile okeere? Nje o tile fe mo siwajusi nipa awon ewu ati orisirisi ona miran to wa nile fun irinajo e si ile okeere? Pe awon olugbaninimonran wa ti won le ran o lowo pelu ifitonileti ati awon otito to ro mon irinajo lo sile okeere ti won yoo si dahun awon ibeere e ni kiakia. A fi da e loju pe gbogbo ipe e ni a o daabo bo. Awon ile ise ibanisoro le yo tasere ninu owo e fun ipe na o.

Kan siwa nipase oju opo ifororanse (email) ti o ba ni ibeere nipa irinajo si ile okeere

Fi email re runse si wa pelu ibeere re okan ninu awon osise wa to jafafa yo si da o loun ni waransesa. A ko si ni fi atejise re sode fun enikeni.

Latest News

Wo gbogbo ẹ

Nigeria: Awọn ilana iṣilọ gbọdọ koju awọn okunfa

Ijoba Naijiria ti ṣe ileri lati dẹkun ise awọn agbeni rinrinajo alaibamu, e yi ni igbiyanju lati dẹkun awọn aṣikiri lati orile-ede Naijiria lati ma ṣe rinrinajo ti o lewu si Europe....
Mọ si

2018, Odun to le gan fun awọn aṣikiri

Awọn to n wa ibi aabo ati awọn aṣikiri ti n rii pe o nira lopolopo lati de ọdọ awọn orilẹ-ede ti o ni aabo ati ati ilọsiwaju ni 2018. Fun awọn ti o pinnu lati de Europe, North...
Mọ si

Ijini gbe, ipọnju ati ijabọ: Irinajo buruku omo Naijiria kan

Lati igba ti ajo ton ri si iṣilọ ni agbaye (IOM) ti bere eto ipadabọ wale aalai ni pa ni May 2017, o koja awọn  7,600 aṣikiri omo orilẹ-ede Naijiria ni o ti pada si Nigeria. Awọn ọdo...
Mọ si