Oku arabinrin omo odun mokanlelogun arinrinajo omo Nigeria ni won ti ri ni agbegbe

Gege bi ifilede ti osu karun lati odo ajo agbaye to n risi lilo lati ilu-silu (IOM), oku ariirinajo omo Naijiria na ni won ri ni ojo kefa osu karun ninu odo Durance leba ona to lewu jojo Alpine towa laarin orile ede Faransi ati Itili.

Omo odun mokanlelogun na loje oku eniyan keji ti won yio ri ni agbegbe na ninu osu karun, banana ni won tun se awari oku arinrinajo miran ni agbegbe Montgenevre, ti ohun na je aresepa laarin orile ede faranse ati Italy bakanna. Siwajusi, ” odomokunrin omo Morocco kan tun ni atejade fi rinle pe o teri sinu odo Kolpa ni ojokokanlelogun osu karun ni enu aala towa ni aarin orile ede Croatia ati Slovenia, eyi gan lo mu ki isele titeri sinu agbami je meje lenu igba ti odun 2018 ti bere.” atejade lati odo IOM fi rinle bee.

Atejade na se agbeyewo ati ilede okanojokan bi awon arinrinajo se n padanu emi won nigbati won ban gbiyanju lati wo ile alawo funfun, eleyi ko yo isele to waye ni ojokejilelogun osu karun ni orile ede Turkey sile nibiti arinrinajo omo orile ede Afghanistan kan ti padanu emi re ninu isele ijamba oko ni Bayramli, eyi to wa ni Van Province, ti ko jina si enu aala ile Greece.

Gegebi ifilede na ti so, “o to aadorin awon arinrinajo Miran tiwon n se irinajo pelu jijoko si eyin oko ajagbe sugbon ti ori ko won yo “.

Atejade ti ajo IOM n se ti fiwe lee pe egberunkan ati ogorun lemerinlelogbon arinrinajo ni won ti ta teru nipa tabi sonu nigbati won n gbiyaju lati won ilu miran ninu odun 2018 Yi, ninu awon wonyi ni awon eniyan egbetaleogoji o din marun ti won padanu emi won sinu okun Mediterranean. Awon Onkowe na fi rinle pe egbaagbeje ounka awon arinrinajo ni won ti jade laye ti a ba fikun ounka to wa nile tele lenu igba die ti a ko se atunko si ohunka naa.

Orisun Aworan: Awon igbimo irinajo la’gbaye gba awon arinrinajo lori okun (http://www.nan.ng/news/iom-recovers-remains-of-woman-migrant/)

TMP – 13/06/2018