Awọn alaṣẹ Libya ti mu awọn aṣikiri ọgọrin ti o lọ si Yuroopu

Ajo International Organization for Migration (IOM), ti sọ pe o ju awọn aṣikiri ọgọrin ti o nlọ si Yuroopu ni, ni ọsẹ to kọja, ni w...
Mọ si

Ijamba ọkọ oju-omi arinrin-ajo akọkọ ni ọdun 2021 pa eyan 43  

Ajo International Organization for Migration (IOM) ati UNHCR ni Ọjọrú sọ pe bii eniyan 43 ni o ku nigba ti wọn gba awọn mẹwa la lẹ...
Mọ si

Wọn ti ri oku awọn arinrin-ajo meje ni eti okun Algeria

Oku awọn ọkunrin mẹta ati awọn obinrin mẹrin ti o gbagbọ pe wọn je arinrin-ajo alaibamu ti n gbiyanju lati de Yuroopu, ni wọn ti r...
Mọ si

Nigeria sowọpọ pelu orilẹ-ede Niger ati Benin lori irin-ajo alaibamu

Ni igbiyanju lati koju gbigbeni rinrin-ajo ati irin-ajo alaibamu ni Nigeria, ajọ Nigeria Customs Services (NCS) sọ pe awon ti ṣe i...
Mọ si

Ọpọlọpọ awọn arinrin-ajo ni igba silẹ ni etikun Tunisia

Bii aadọta awọn arinrin-ajo lati oriṣiriṣi orilẹ-ede Afirika ni ẹsọ oju-omi ti Tunisia ti gbala lehin ọjọ marun lori okun, Ile-iṣẹ...
Mọ si

O ju ọgọ́rùn ọmọ Naijiria tí o ni iṣoro ni Niger pada wale

Awon 109 ọmọ  Naijiria 109 ti o ni iṣoro ni Niger Republic nitori titipa ala nitori ajakaye-arun COVID-19 ti pada si orilẹ-ede Nai...
Mọ si

Ijamba Oju-omi: Ajọ Libyan Red Crescent ṣe awari oku awọn ọmọ mẹrin

Ara awọn ọmọ mẹrin bii ọdun marun si mẹwa ni wọn ti ṣe awari ni eti okun omi Libyan lẹhin ti ọkọ oju omi arinrin-ajo kan rì ni ọjọ...
Mọ si

IOM mu awọn arinrin-ajo 16,800 ọmọ Naijiria pada si’le laarin ọdun mẹta

Ajọ International Organization for Migration (IOM) ti mu awọn arinrin-ajo alaibamu 16,800 pada si’le lati Yuroopu si Nigeria laari...
Mọ si

Ikilọ fun awọn ọmọ Naijiria lori irin-ajo alaibamu

Wọn ti rọ awọn ọmọ Naijiria, ni pataki ọdọ, lati dawọ lati bẹrẹ irin-ajo ti kii ṣe deede nitori awọn irin-ajo jẹ eewu pupọ ati pe ...
Mọ si