Everything you need to know about Covid 19

Alaye Nipa Irinajo
Lojoojumọ, awọn eniyan ṣe ipinnu ti o nira lati fi awọn ibugbe wọn silẹ ni Nigeria ni wiwa ọjọ-iwaju to dara julọ. Ọpọlọpọ n fi ẹmi wọn wawu ni gbiyanju lati de Ilu Europe nipasẹ Libya.
Njẹ o n ronu lati rin rinajo tabi o ti rinrin ajo na tele? Kọ ẹkọ diẹ sii nipa awọn ona re ti ba ofin mu ati awọn ewu ti irinajo alaibamu lati ṣe iranlọwọ fun ọ lati ṣe ipinnu ti o ni alaye lori irinajo.
Pe awọn amoye irinajo wa fun ododo oro nipa irinajo
Lati ọjọ Mọnday si ọjọ Friday (Ago mesan aro titi di ago merin irọlẹ)
To ba je ede Yoruba, Pidgin tabi Gẹẹsi +234 816 922 9349
To ba je ede Gẹẹsi tabi Pidgin +234 806 163 7956
O tun le lo WhatsApp ati awọn ifiranṣẹ.
Gbogbo ipe ni aabo.
Orisirisi idi ni o wa ti awọn eniyan ṣe n se ipinnu ti o nira lati fi awọn ile wọn silẹ. Awọn die n salọ fun inunibini nigba ti aw...
Nje iwọ tabi ẹnikan ti o mọ n gbero lati rin rinajo si Europe ni ona alaibamu? Ni ọrọ miiran, se iwọ n ronu lati rinajo si Europe ...
Ni gbogbo ọdun, ẹgbẹẹgbẹrun eniyan n gbiyanju lati jade lọ si orilẹ-ede miiran laisi aṣẹ fisa tabi iyọọda to wulo. Ọpọlọpọ ko ni o...
Ọpọlọpọ awọn arinrinajo alaibamu ma n lọ si Europe pelu ireti ọjọ iwaju to dara julọ. Sugbon otito bee ma n yaatonati wipee pupọ n...
Pin lori