Awọn Arokọ Tuntun

Wo gbogbo ẹ

Ajo Isokan agbaye UN se itaniloji fun awon afinisowo ni orile ede Libiya

Mefa ninu awon olori itakun afinisowo ni orile ede Libya ni eka eto aabo ninu ajo isokan agbaye ti ta loji bayi. Eleyi ni igba akoko ti awon afinisowo na yo di mimenuba ninu iwe itaniloji ajo na....
Mọ si

Oku arabinrin omo odun mokanlelogun arinrinajo omo Nigeria ni won ti ri ni agbegbe

Gege bi ifilede ti osu karun lati odo ajo agbaye to n risi lilo lati ilu-silu (IOM), oku ariirinajo omo Naijiria na ni won ri ni ojo kefa osu karun ninu odo Durance leba ona to lewu jojo Alpine towa...
Mọ si

Egbegberun awon omo Naijiria ni won ti da pada sile lati Libya

Egberunmeje le ni ojileleedegberin ati mefa awon omo orile ede Naijiria ni won ti da pada sile lati orile ede Libya labe akitiyan ajo agbaye to n risi irinajo (IOM) ifinufindo ati ifimonle, eyi ti...
Mọ si

Aye n te si waju

Aye n te si waju – opolopo awon eniyan lo n rinrinajo lati ilukan bosikan lowolowo, beni opolopowon londojuko ipenija to lagbara ninu irin ajo won ni aye ode yi.

A o pese awọn otitọ ati iroyin to n sele lowolowo lori irinajo ni orisirisi ede ti yoo wa ni arowoto awon arinrinajo.

Mọ si