Pipese awn odd pataki nipa irin-ajo alaibamu

Ti o ba n ronu lati rin rin-ajo lo si oke okun abi o ba ti wa ni na, eto Migrant Project le fun ni awn alaye pataki ti o se gbkle ni f. A le s awn eewu ti o wa lona fun ki o to br irin-ajo r, ati bi igbesi aye e ri ni tooto ni awn oril-ede irin-ajo kaakiri. A tun le ran lw lati m nipa awn ona lati rin rin-ajo to ba ofin mu, ikk tabi awn aye iowo ti o sunm .

Awn alaye to se gbkle nipa irin-ajo si oril-ede titun soro lati ri. Awn iroyin, agbeni rin rin-ajo, ati paapaa awn eniyan to wa ni agbegbe r ti won ti rinrin-ajo ri tl le funni ni imran ati alaye ti ko n se otito lori irin-ajo ati igbesi aye ni oril-ede titun. Awn agbeni rin rin-ajo yoo par lati gba owo. Ati pe ohun ti o j otit fun arin rin-ajo kn tele le ma j be loni – awn ofin ni awn oril-ede ma yipada, ati awn ipa-na le ni eewu sii.

Awn agbani nimran agbegbe wa le fun e ni awn alaye ododo to o le gbkle yala ti o ba n gbero lati rin rin-ajo lo si oke okun tabi ti o ba ti wa ni na. Eyi le je sisro ni ojukoroju tabi lori foonu, nibi ti awn oiṣẹ wa ti le dahun awn ibeere r. Awn ibara nisr wnyi j oun ipamo nigbagbogbo. A tun ma n pese alaye lori ayelujara nipas oju-iwe Facebook wa. O tun si le lo si awn eto wa ni agbegbe r ki o to e ipinnu konkon nipa irin-ajo lo si ilu oke okun.

Eni Ti A J

Eto Migrant Project ni ero lati pese alaye otito ati ododo lori irin-ajo alaibamu, lati le se iran lowo fun awn arin rin-ajo ati wn ti o ni ife lati rin rin-ajo se ipinu to kun na. A n pese awn otito ati iroyin lwlw lori irin-ajo lo si oke okun ni awn ede pup, fun awn ti o wa ni ile tabi ni irin ajo.

A nlo awn ona ti o rrun lati wle si ibi awon ibi to gbajugbaja jul laarin awn agbegbe arin rin-ajo. Eyi plu awn laini foonu nibiti awn arin rin-ajo le ba  awon agbani nimoran wa sr ni ede tiwn; oju ewe wẹẹbu ti iapeye fun lil lori foonuiyara kan; social media; ati awn eto alaye ni awn agbegbe agbegbe. Eto Migrant Project wa ni Asia, Aarin Ila-oorun, Afirika ati Yuroopu, in ona to da.

TMP Nigeria receives funding from the Asylum, Migration and Integration Fund (AMIF) of the European Union and the Federal Ministry of the Interior of the Republic of Austria.


European Union Austria