Igbimọ ṣe ifilọlẹ ipolongo tuntun lati koju irin-ajo alaibamu

Ni ọna lati jẹ ki awọn ọdọ Afirika mọ awọn eewu ti o wa ninu irin-ajo alaibamu si Yuroopu, Igbimọ...
Mọ si

Aja ọlọpa Ilu Spain ri awọn aṣikiri marun ti wọn sapamọ sinu apo

Awọn ọmọ ẹgbẹ Spanish Civil Guard, pẹlu iranlọwọ aja ọlọpa kan, ti mu awọn ọkunrin marun ti o...
Mọ si

Awọn oludari Afirika gbọdọ koju irin-ajo alaibamu, ajọ JIFORM lo sọ eyi

Awọn adari ile Afirika gbọdọ koju idi aini ati oṣi ti o fa irin-ajo alaibamu, eyi ni ajọ Journalists...
Mọ si

UN tun ti bẹrẹ lati ma mu awọn aṣikiri pada sile lati Libya

Awọn ọkọ ofurufu lati mu awọn aṣikiri ti ni iṣoro ni Ilu Libya tun ti bẹrẹ, ajọ Agbaye fun ọro...
Mọ si

Aṣikiri mẹdogun ku lehin ijamba ọkọ oju-omi ni eti okun Libya

Bii awọn aṣikiri mẹdogun ti n gbiyanju lati de Yuroopu ti rì sinu Okun Mẹditarenia ni etikun Libya, ajọ...
Mọ si

Awọn aṣikiri ti o wọ erekusu Canary ti Spain ni ọdun yii pọ ju lati ọdun 2006

O ju 1,000 awọn aṣikiri lati Afirika ti o wọle si awọn erekusu Canary ti Spain laarin wakati mejidiladọta, ni...
Mọ si

Lebanon yoo mu awọn aṣikiri alaibamu ti nlọ si Cyprus

Lebanoni ti tun fi idi rẹ mulẹ lati mu ati da awọn aṣikiri alaibamu ti nlo si Cyprus lori ọkọ-oju omi pada....
Mọ si

Wọn dana sun arinrin-ajo ọmọ Naijiria ni orilẹ-ede Libya

Arakunrin ọmọ orilẹ-ede Naijiria kan ti n ṣiṣẹ ni ile-iṣẹ kan ni Tripoli, Libya ni awọn ọkunrin...
Mọ si

Pope Francis pe fun atilẹyin awọn aṣikiri

Pope Francis ti rọ gbogbo agbaye lati gbadura ati ṣe atilẹyin fun awọn aṣikiri, awọn asasala ati awọn...
Mọ si