Category: Yuroopu


2018, Odun to le gan fun awọn aṣikiri

Awọn to n wa ibi aabo ati awọn aṣikiri ti n rii pe o nira lopolopo lati de ọdọ awọn orilẹ-ede ti o ni aabo ati ati...
Mọ si

Ijini gbe, ipọnju ati ijabọ: Irinajo buruku omo Naijiria kan

Lati igba ti ajo ton ri si iṣilọ ni agbaye (IOM) ti bere eto ipadabọ wale aalai ni pa ni May 2017, o koja awọn  7,600...
Mọ si

Italy se ofin titun ti o sọ awọn aṣikiri di alaini ile ati aabo

Ọpọlọpọ awọn aṣikiri ti o wa ni Italia ni wọn n le lọ si awọn oju ona lai ni aabo lẹhin ti awọn ile asofin...
Mọ si

Awon agbeni rinrinajo alaibamu ni o se opolopo iwa-ipa ati ilokulo si awọn aṣikiri

Awọn agbeni rinrinajo alaibamu (smugglers) ni o ni idajọ fun ida aadọta ninu awọn iṣẹlẹ ti iwa-ipa ibalopo, iwa-ipa...
Mọ si

Germany sowopo pẹlu Nigeria lori irinajo alaibamu

Gegebi awọn ọna lati dinku oṣuwọn iṣoro ti irinajo si Europe, Germany ati Nigeria ti fi enu ko lori adehun mẹta (MoU)...
Mọ si

Egbeegberun awon arinrinajo omo orile ede Nigeria ni won fi’pa mu sise asewo ni orile ede Italy

Egbeegberun awon omo orile ede Nigeria ni won fi ipa mu lati se ise asewo lodoodun ni orile ede Italy, eni ti o je adari agba fun...
Mọ si

Eto imulo ajo isokan ile alawofunfun EU: Iha wo lo ko si ile Afirika

Ajo ile alawofunfun EU ti n se akitiyan olokan o jokan lati wa ojutu kan gbogi si isoro ominlengbe awon arinrinajo ti ko...
Mọ si

Awon arinrinajo ti won ti ku lori okun Mediterranean ju egberun kan lo ninu abala akoko odun 2018

O le ni egberun kan awon arinrinajo ti iroyin fi mule pe won ti ta teru nipa nigba ti won n gbiyanju lati rekoja lori okun...
Mọ si

Ile geesi ati Naijiria yo fowosowopo gbogun ti irinajo lona aito ati ifinisowo

Ijoba ile geesi ti so di mimo pe ohun yo kun orile ede Nigeria lowo ninu akitiyan re ninu gbigbogunti ati fi fi iya je awon...
Mọ si