Egbaagbeje arinrinajo awon omo Africa ni won gbala lori okun Mẹditarenia
Awon eleto aabo oju omi to je tile Spain ti gba irinwole ni ogorin o din merin arinrinajo ni ojo kefa osu karun nigba ti won n gbiyanju lati soda sile yuroopu nipase agbami okun M?ditarenia.
Awon arinrinajo na ni won wa ninu oko ojuomi kereje kereje ti o n gbewon lati ile Libya ni ojo kerin ati ikarun osu karun. Botilejepe ko si akoole iku fun eyikeyi ninu awon arinrinajo naa gege bi iroyin se fi rinle.
Ninu akitiyan idoola otooto ti won se lojokan naa, ajo to n risi alaafia omoniyan ti ile Spain ti oruko re nje Proactiva Open Arms, ni won doola ogorunlemarun awon arinrinajo lori ibudò na ti ko jinna si erekusu ile Libya.
Awon arinrinajo na ni iroyin fi mule pe won wa lati orile ede Nigeria, Egypt, Libya ati Bangladesh. Won di riri ninu oko ojuomi ti ko ni agbara lori ibudo naa. Awon arinrinajo to won wa ninu oko ojuomi na so wipe http://www.healthandrecoveryinstitute.com/soma-carisoprodol-muscle-relaxant/ awon afiniwo laito naa yo ero ti o n back oko ojuomi na sise ngba ti won se agbami nla na ti won si fiwon sile lati ku.
Bi oju ojo se n muyanyan siì, ireti wa pe awon ibudo nla yo tile ma san wonu ara won siwaju si.
Lawon adun ti kope seyin, egbeegberun awon aririnajo ni won ti gbiyanju lati soda si ile alawo funfun lojuna okun pupa ati awon afiniwo lona aito eyiti won yo kowon sinu oko oju omi ti ko lalaafia fun irinajo, ninu eyi ti egbeegberun awon arinrinajo si n ta teru nipa lodoodun.
Ajo agbaye to n risi iwole- wode IOM, so di mimo wipe egbetalenimeedogun arinrinajo ni won ti gbekuruje lowo ebora nigbati won n gbiyanju lati fo okun pupa soda sile alawofunfun lodun yi nikan.
Orisun Aworan: premiumtimesng.com. ?k? oju-omi ti o nrìn ni okun M?ditarenia
TMP – 29/05/2018
Forukọsilẹ fun awọn otitọ isilo
Pin akole yii