Awon arinrinajo ti won ti ku lori okun Mediterranean ju egberun kan lo ninu abala akoko odun 2018
O le ni egberun kan awon arinrinajo ti iroyin fi mule pe won ti ta teru nipa nigba ti won n gbiyanju lati rekoja lori okun Mediterranean lo si ile alawo funfun ninu abala akoko odun 2018. O le ni igba awon arinrinajo ti won teri ninu ojo meta akoko ninu osu keje, gege bi ajo agbaye to n risi igbokegbodo irinajo (IOM) se so.
Ni ojo kinni osu keje, awon eso erekusu ti orile ede Libya jabo wipe ogorun eniyan ni won wati nigbati oko ojuomi oniroba kekere kan ti o awon arinrinajo teri l’eba erekusu Tripoli. Ajo IOM jabo pe mokanlelogoji eniyan pere ni won ye ninu isele na pelu akitiyan idoola won.
Oko ojuomi miran tun baje loju omi ni ojokejidinlogbon osu kefa nibiti metalelogorun eniyan ti ku, ninu eyi ti ati ri omo owo meta, eyi waye nipase “awon afinisowo ti won n mu awon arinrinajo gba ori omi pelu awon oko ti o lewu jojo,” ifilede lati odo ajo IOM lo see lalaye bee.
Ninu odun yi, o ti le ni egberun mewa awon arinrinajo ti awon eleto aabo erekusu Libya ti da pada si ebute leyin igba ti won ti doola won ninu okan ojokan oko oju omi kereje-kereje.
Gege bi atejade lati odo ajo IOM se so o fee to egberun kan awon arinrinajo ti awon aleto abo orile ede Libya da pada si ebute orile ede na lari ojo eti si ojo aiku. Ajo IOM tile se iranlowo taara fun awon ti won doola na pelu ounje ati omi, iranlowo nipa ilera leyin na ni awon alase orile ede Libya ko won lo si ibudo ifiniwo nigbati ajo IOM si n te siwaju ninu iranlowo re.
Eni toje oga eleto na lati inu ajo IOM ni ilu Libya, Othman Belbeisi so pe ” iku omi tile n lekun sii ni eba erekusu Libya. Awon afinisowo tile n diyele ife dandan wooko awon arinrinajo lati rekoja okun na ki awon ile alawofunfun to se igbese to lagbara lori rirekoja wolu nipase okun Mediterranean na “.
“Awon arinrinajo ti awon alaabo erekusu ba doola Ni won ko gbodo ma ko losi ibudo ifiniwo ni kiakia nitoripe a n kominu pe ibudo na yo ti kun ju boseye lo atipe igbayegbadun nibe yo ti dinku jojo pelu bi egbaagbeje awon arinrinajo ti se ni farahan “, Belbesi fikun oro re.
Ninu igbiyanju won lati je anfani eto oro aje to fidimule, egbaagbeje awon omo ile alawo dudu Africa ni won n gbiyaju lati wo ile alawofunfun nipase gbigba ona to lewu pupo lati gba ori okun Mediterranean ati awon orile ede ariwa ile Africa.
TMP – 02/08/2018
Orisun Aworan: www.aa.com.tr
Pin akole yii