Griisi: Ẹgbẹẹgbẹrun awọn aṣikiri di alainile lẹhin ti ina jo ibudó Moria

Bii awọn aṣikiri 13,000 ni ko ni ile mọ lẹhin ti awọn ina ti nyara jo ibudó aṣikiri nla julọ ni Yuroopu...
Mọ si

Naijiria: Ipinle Eko ṣe idasile ẹgbẹ agbofinro lori ifipa gbeni rinrin-ajo

Ninu igbiyanju lati dẹkun iwaa ifipa gbeni rinrin-ajo (human trafficking) ni Ipinle Eko, Gomina Babajide Sanwo-Olu ti...
Mọ si

Arinrin-ajo ogún ku ni ọsẹ kan ni erekusu Canary

Awọn arinrin-ajo ogún padanu ẹmi wọn ni ọsẹ to kọja nigba ti wọn n gbiyanju lati rinrin-ajo alaibamu...
Mọ si

Libiya: Wọ́n ti rí òkú mejilelogun ní eti okun Zwara

Ni ọjọ ketalelogun oṣu kẹjọ, wọn ri oku awọn arinrin-ajo mejilelogun ni eti okun ti Zwara ni Ilu Libiya,...
Mọ si

Eyi ni ijamba ọkọ oju-omi ti o buru ju lori okun Mẹditarenia ni ọdun 2020

O to marundinladọta awọn aṣikiri ti n lọ si Yuroopu, ni o ti ku ninu ninu jamba ọkọ oju-omi lori okun...
Mọ si

Orilẹ-ede Morocco ati Pọtugali fọwọsowọpọ lori iṣikiri

Orilẹ-ede Morocco ati Pọtugali n gbero lati fọwọsowọpọ sii lati dekun iṣikiri alaibamu ni ọjọ iwaju,...
Mọ si

Wọn ti ri ara ọmọ’kunrin arinrin-ajo kan ni eti okun Faranse

Wọn ti ri ara ọmọ’kunrin merindilogun kan ti o ku sinu okun ni eti Faranse nigbati oun gbiyanju lati de Ilu...
Mọ si

Bi ọgọrun ọmọ obinrin Naijiria ti o ni iṣoro ni Lebanoni pada si ile

Awọn mẹrinlelaadọrun ọmọ obinrin orile-ede Naijiria ti o ni iṣoro ni Lebanoni ti pada si ile lẹhin ti...
Mọ si

“Yuroopu ko le kuna lẹmeji lori irin-ajo” – Ajọ Yuroopu

Igbakeji-Alakoso ajọ European Commission, Margaritis Schinas, laipe pe awọn ọmọ ẹgbẹ Yuroopu lati yago fun...
Mọ si