Faranse fi opin si ibudo awọn arinrin-ajo ni ariwa Paris

Awọn ọlọpa Faranse ti mu awọn arinrin-ajo 427 miiran kuro ni ibudo afowohe ti o kẹhin ni ariwa ila-oorun...
Mọ si

Ile-ẹkọ kan ni Netherlands ngbero lati se eto irin-ajo fun awọn Naijiria ti o ni ise ọwọ

Ninu ipa lati dẹkun irin-ajo alaibamu lati Nigeria, Ile-ẹkọ Ibatan Kariaye ti Ilu Netherlands ti sọ wi pe oun...
Mọ si

O koja 1,000 awọn arinrin-ajo ti o gbiyanju lati de Yuroopu lati Libiya ni ọsẹ meji akọkọ ti 2020

O ju 1,000 awọn arinrin-ajo ni o kuro ni etikun Libya ni ọsẹ meji akọkọ ti 2020 ninu igbiyanju lati de...
Mọ si

Naijiria fowo si adehun lati dekun irin-ajo alaibamu

Ni ibamu pelu awọn ipa lati dẹkun irin-ajo alaibamu ni orilẹ-ede Naijiria, ijọba apapo ti fowo si adehun pẹlu...
Mọ si

Irin-ajo alaibamu si Yuroopu dinku si kekere julo lati ọdun 2013

Apapọ arinrin-ajo 127,657 ni o wọ Yuroopu ni ona alaibamu ni ọdun 2019, eyi ti o tunmo si pe irin-ajo alaibamu si...
Mọ si

O ju 120 arinrin-ajo ti wọn gbala ni wọn ti je ji wọn wo Itali lẹyin igba pipẹ ni ori okun

Ọkọ oju-omi nla meji gbe awọn arinrin-ajo 121 wa si awọn ebute oko oju omi meji ni Sicily, Italy, ni ọjọ...
Mọ si

Arinrin-ajo mẹjọ ku sinu okun laarin wakati merinlelogun ninu igbiyanju lati de ilu Spain

Ara awọn arinrin-ajo mẹjọ ni a ri laarin wakati merinlelogun ni oṣu kejila ni eti okun Spain. Wọn wa lara...
Mọ si

Ijọba Naijiria se àìníyàn nipa ọpọlọpọ awọn omo Naijiria to fe rin rinajo alaibamu

Minisita fun Eto Eda Eniyan ti Ilu Naijiria, Isakoso Ajalu ati Idagbasoke Awujọ, Sadiya Umar Farouq, ti ṣalaye...
Mọ si

Bi 16,000 awọn ọmọ Naijiria pada si ile lati orilẹ-ede mẹrindilogun lati oṣu kẹrin ọdun 2017

Apapọ 15,731 awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria ti pada si ile lati awọn orilẹ-ede mẹrindilogun lati oṣu...
Mọ si