Egbeegberun awon arinrinajo omo orile ede Nigeria ni won fi’pa mu sise asewo ni orile ede Italy

Egbeegberun awon omo orile ede Nigeria ni won fi ipa mu lati se ise asewo lodoodun ni orile ede Italy, eni ti o je...
Mọ si

Won gba opolopo awon arinrinajo la leba erekusu orile ede Libiya

Ko din ni ogofa odinmarun awon arinrinajo ni won ti doola leba ila oorun erekusu Libya ni owo ibere osu keje. Ifilede...
Mọ si

Ajo NAPTIP n fe lati ma f’ofin mu awon afinisowo l’awon bode

Ajo orile ede Nigeria to n gbogun ti ifiniyan sowo, ajo orile ede to n dena ifinisowo (NAPTIP), ti pe fun ifofinmu ati...
Mọ si

Eto imulo ajo isokan ile alawofunfun EU: Iha wo lo ko si ile Afirika

Ajo ile alawofunfun EU ti n se akitiyan olokan o jokan lati wa ojutu kan gbogi si isoro ominlengbe awon arinrinajo ti...
Mọ si

Awon arinrinajo ti won ti ku lori okun Mediterranean ju egberun kan lo ninu abala akoko odun 2018

O le ni egberun kan awon arinrinajo ti iroyin fi mule pe won ti ta teru nipa nigba ti won n gbiyanju lati rekoja lori...
Mọ si

Ile geesi ati Naijiria yo fowosowopo gbogun ti irinajo lona aito ati ifinisowo

Ijoba ile geesi ti so di mimo pe ohun yo kun orile ede Nigeria lowo ninu akitiyan re ninu gbigbogunti ati fi fi iya je...
Mọ si

Orile ede Hungari ti se ofin ti yo ma so awon oluranlowo ati agbodegba awon oluwo ti ko b’ofinmu di odaran

Ni ogunjo osu kefa odun yi, ile asofin ti orile ede olominira Hungari so awon aba kan ti yo ma so enikeni tabi ajo...
Mọ si

Eto ise aso riran fun awon arinrinajo obinrin ni ile ise Gucci ti ta lore ebun ebayi

Isi awon obinrin lati orile ede Nigeria ti awon kan ko wole laibofunmu wo ile Italy fun owo eru tipatipa ni won ti ri...
Mọ si

Ajo Isokan agbaye UN se itaniloji fun awon afinisowo ni orile ede Libiya

Mefa ninu awon olori itakun afinisowo ni orile ede Libya ni eka eto aabo ninu ajo isokan agbaye ti ta loji bayi. Eleyi...
Mọ si