Awọn arinrin-ajo tako ihamọ fun ọjọ pipẹ in Niger

Ọgọọgọrun awọn arinrin-ajo Afirika ti o ni idaduro ni Niger ti lọ si awọn opopona lati ṣe atako si...
Mọ si

Wọn gba Jẹmani ni imọran lati ṣeto owo fun fisa fun awọn arinrinajo lati Afirika  

O yẹ ki Jẹmani ṣeto ilana iwe iwọlu nipasẹ eyiti ti awọn arinrinajo Ilu Afirika le gba ni iwe iṣẹ igba...
Mọ si

Ẹgbẹẹgbẹrun awọn arinrin-ajo ni idaduro ni ilu Niger nitori coronavirus

O ju 2,300 awọn arinrin-ajo lọ, pupọ ninu wọn ti o jẹ ọmọ orilẹ-ede Naijiria, Mali, Guinea ati...
Mọ si

Iwọle si Yuroopu nipasẹ okun Mẹditarenia ni ọdun 2020 ti ju ọdun 2019 lọ

Ọpọlọpọ awọn arinrin-ajo ti wọ Yuroopu nipasẹ okun ni ọdun yii ju ọdun to kọja lọ, bẹni ajọ...
Mọ si

Ọmọ Nàìjíríà gba ẹ̀bùn iṣẹ́ ìrìn-àjò

Chidi Nwaogu, ọdọmọkunrin kan lati Nigeria, ti gba ẹbun fun iṣẹ irin-ajo eyi ti ajo Human Security Division...
Mọ si

Awọn arinrinajo pada si Libiya larin ija

O ju aadọta awọn arinrin-ajo ti wọn gbala ni ori omi Maltese ni wọn da pada si Tripoli, Libya laarin wahala ati...
Mọ si

Malta nwa ilowosi EU ninu wahala Libiya

Malta ti dabaa pe ki ajọ European Union (EU) ṣẹda owo ilowosi miliọnu 100 EURO lati dawọ awọn ajalu omo...
Mọ si

Faranse: Awọn arinrinajo wa ninu inira bi arun coronavirus se n pọsi

Ẹgbẹẹgbẹrun awọn arinrinajo ati asasala ṣin sùn si ita gbangba larin ajakaye-arun coronavirus ati titiipa...
Mọ si

Ọkọ oju-omi pẹlu 150 awọn arinrin-ajo ni iṣoro lori okun Mẹditarenia

O to 150 awọn arinrin-ajo ni wọn gbala lati ni Mẹditarenia lẹhin awọn iṣẹ igbala meji otọtọ ti...
Mọ si