Bi 160 awọn ọmọ Naijiria ti o ni idaduro ni orilẹ-ede Niger ti pada wale

Awọn aṣikiri 158 ọmọ orilẹ-ede Naijiria ti o idaduro ni orilẹ-ede Niger ti pada wale. Awọn aṣikiri, ti o de si papa ọkọ ofurufu Nn...
Mọ si

Awọn ọmọbirin lati Naijiria ti o ni ihamọ ni Lebanoni bẹbẹ lati wale

O to ọgbọn awọn ọmọbirin Naijiria ti o ni ihamọ ni Lebanoni ti pe ijọba ti Naijiria ati awọn alabaṣepọ miiran lati ṣe iranlọwọ fun...
Mọ si

O yẹ ki Yuroopu dekun didapada awọn aṣikiri si Libya, IOM lọ sọ bẹ

Ni ọsẹ to kọja, ajọ International Organisation for Migration (IOM) pe Yuroopu lati dekun didapada awọn aṣikiri ti a gbala si Libiy...
Mọ si

Ẹ̀ṣọ oju-omi ni Libya mu ọgọrin-mẹta aṣikiri ti nlọ si Yuroopu

O tọ ọgọrin-mẹta awọn aṣikiri lori ọkọ oju-omi ti nlo si Yuroopu ni ọjọ kejila oṣu keje ni awọn eṣọ oju-omi ni Libiya ti mu lọ si ...
Mọ si

Niger lé ogoji ọmọ Naijiria ti nlọ si Yuroopu pada wale  

O to ogoji ati meji awọn ọmọ Naijiria ti o wa ni ọna lọ si ilu Yuroopu ni orile-ede Niger ti lé pada si Naijiria. Awọn apada wale ...
Mọ si

Aadọta aṣikiri ti ku lehin ti ọkọ oju-omi wọn rì ni Tunisia  

Ọkọ oju-omi kekere kan ti o lọ si Ilu Italy rì ni oṣu to kọja nitosi ilu Ilu Sfax ti Tunisia. Iṣẹlẹ yi pa awọn eniyan ti o aadọta....
Mọ si

Awọn aṣikiri n gbe ninu ‘apaadi’ ti a ko le foju ri ni Libya, Pope Francis lo sọ bẹ

Pope Francis ti ṣapejuwe igbesi aye awọn aṣikiri ati asasala ti o wa ninu atimọle kaakiri Libya bi igbe aye ti ‘apaadi’. Ẹgb...
Mọ si

Morocco mu mẹta-le-logun awọn aṣikiri alaibamu ti oun lo si Yuroopu

Ko kere ju mẹta-le-logun awọn aṣikiri alaibamu ti a ko mọ orilẹ-ede wọn ni olopa Morocco ti mu ni Ojo Kerindinlogun Oṣu Kefa. Ẹgbẹ...
Mọ si

Morocco da 74,000 arinrin-ajo alaibamu duro ni ọdun 2019

Ilu Morocco sọ pe awọn ẹṣọ aabo rẹ da awọn arinrin-ajo pelu igbiyanju ona alaibamu ti o to 74,000 duro ati 208 aparapọ awọn ajinig...
Mọ si