O ju irinwo awọn arinrinajo ti won ni igbala kuro ninu aginjù Sahara

O ju irinwo awọn arinrinajo ti o nrìn pelu ẹsẹ ni awọn ẹgbẹ igbimọ ati awọn ẹgbẹ igbapada ti o wa ni agbegbe Niger-Algeria, gbe so...
Mọ si

Germany sowopo pẹlu Nigeria lori irinajo alaibamu

Gegebi awọn ọna lati dinku oṣuwọn iṣoro ti irinajo si Europe, Germany ati Nigeria ti fi enu ko lori adehun mẹta (MoU) lati mu awọn...
Mọ si

Won gba opolopo awon arinrinajo la leba erekusu orile ede Libiya

Ko din ni ogofa odinmarun awon arinrinajo ni won ti doola leba ila oorun erekusu Libya ni owo ibere osu keje. Ifilede na ni awon...
Mọ si

Ajo NAPTIP n fe lati ma f’ofin mu awon afinisowo l’awon bode

Ajo orile ede Nigeria to n gbogun ti ifiniyan sowo, ajo orile ede to n dena ifinisowo (NAPTIP), ti pe fun ifofinmu ati ifiyaje...
Mọ si

Ile geesi ati Naijiria yo fowosowopo gbogun ti irinajo lona aito ati ifinisowo

Ijoba ile geesi ti so di mimo pe ohun yo kun orile ede Nigeria lowo ninu akitiyan re ninu gbigbogunti ati fi fi iya je awon...
Mọ si

Eto ise aso riran fun awon arinrinajo obinrin ni ile ise Gucci ti ta lore ebun ebayi

Isi awon obinrin lati orile ede Nigeria ti awon kan ko wole laibofunmu wo ile Italy fun owo eru tipatipa ni won ti ri ise tuntun...
Mọ si

Egbegberun awon omo Naijiria ni won ti da pada sile lati Libya

Egberunmeje le ni ojileleedegberin ati mefa awon omo orile ede Naijiria ni won ti da pada sile lati orile ede Libya labe akitiyan...
Mọ si