Ọwọ ba awọn mejila ti n ṣiṣẹ oogun oloro ati irin-ajo alaibamu ni orilẹ-ede Morocco

Ni ọsẹ to kọja, ọlọpa orilẹ-ede Morocco mu awọn mejila ni Agadir fun ẹsun lilọwọ si gbigbe oogun olori, irin-ajo alaibamu ati ifip...
Mọ si

Naijiria: Ipinle Eko ṣe idasile ẹgbẹ agbofinro lori ifipa gbeni rinrin-ajo

Ninu igbiyanju lati dẹkun iwaa ifipa gbeni rinrin-ajo (human trafficking) ni Ipinle Eko, Gomina Babajide Sanwo-Olu ti ṣagbekalẹ Ẹg...
Mọ si

Arinrin-ajo ogún ku ni ọsẹ kan ni erekusu Canary

Awọn arinrin-ajo ogún padanu ẹmi wọn ni ọsẹ to kọja nigba ti wọn n gbiyanju lati rinrin-ajo alaibamu lori okun lati Iwọ-oorun Afir...
Mọ si

Libiya: Wọ́n ti rí òkú mejilelogun ní eti okun Zwara

Ni ọjọ ketalelogun oṣu kẹjọ, wọn ri oku awọn arinrin-ajo mejilelogun ni eti okun ti Zwara ni Ilu Libiya, ajọ International Organis...
Mọ si

Orilẹ-ede Morocco ati Pọtugali fọwọsowọpọ lori iṣikiri

Orilẹ-ede Morocco ati Pọtugali n gbero lati fọwọsowọpọ sii lati dekun iṣikiri alaibamu ni ọjọ iwaju, ni ibamu si adehun ti a ṣe la...
Mọ si

Wọn ti ri ara ọmọ’kunrin arinrin-ajo kan ni eti okun Faranse

Wọn ti ri ara ọmọ’kunrin merindilogun kan ti o ku sinu okun ni eti Faranse nigbati oun gbiyanju lati de Ilu United Kingdom, awọn a...
Mọ si

Bi ọgọrun ọmọ obinrin Naijiria ti o ni iṣoro ni Lebanoni pada si ile

Awọn mẹrinlelaadọrun ọmọ obinrin orile-ede Naijiria ti o ni iṣoro ni Lebanoni ti pada si ile lẹhin ti wọn ke si ijọba ilu Naijiria...
Mọ si

O to 7,000 awọn aṣikiri ni wọn ti mu pada si Libya ni ọdun 2020

Awọn 6,848 aṣikiri alaibamu ti n gbiyanju lati de Ilu Yuroopu nipasẹ okun Mẹditarenia ni wọn ti mu pada si Libya ni ọdun 2020, bẹẹ...
Mọ si

Iranlọwọ ọfẹ yoo to bẹrẹ ni Naijiria fun awọn tó ye ifipa gbe eniyan rinrin-ajo

Ajọ International Organization for Migration (IOM) ti kede ṣiṣi ibudo tuntun ni Ipinle Edo lati pese iranlọwọ ofin ni ọfẹ fun awọn...
Mọ si