Category: Ile Libiya


Nigeria: Awọn ilana iṣilọ gbọdọ koju awọn okunfa

Ijoba Naijiria ti ṣe ileri lati dẹkun ise awọn agbeni rinrinajo alaibamu, e yi ni igbiyanju lati dẹkun awọn aṣikiri...
Mọ si

Ijini gbe, ipọnju ati ijabọ: Irinajo buruku omo Naijiria kan

Lati igba ti ajo ton ri si iṣilọ ni agbaye (IOM) ti bere eto ipadabọ wale aalai ni pa ni May 2017, o koja awọn  7,600...
Mọ si

Awọn arinrinajo alaibamu lati ariwa Nigeria sọrọ lori ijiya wọn ni Libya

Ọrọ irinajo alaibamu ti di ọrọ pataki ni Nigeria. Nigbati ti ọpọlọpọ awọn itọka ti ṣe ifojusi si awọn...
Mọ si

Ẹgbẹ kan pe fun idasile awọn arinrinajo alaibamu lati Naijaria ti o wa ni ati mole ni orile-ede Libiya

Ilana Imudarasi Iṣilọ Nigeria (MEPN) ti rọ Ijọba Naijiria lati beere fun idasile awọn ọmọ orile-ede Naijiria ti o...
Mọ si

O ju egberun mewa awọn arinrinajo Naijiria ti o pada wale lati Libiya

O ju egberun mewa awọn arinajo ọmọ Naijiria ti o ni isoro ni ilu Libiya ni wọn ti pada si ilu won laarin oṣu kẹrin...
Mọ si

Won gba opolopo awon arinrinajo la leba erekusu orile ede Libiya

Ko din ni ogofa odinmarun awon arinrinajo ni won ti doola leba ila oorun erekusu Libya ni owo ibere osu keje. Ifilede na ni awon...
Mọ si

Egbegberun awon omo Naijiria ni won ti da pada sile lati Libya

Egberunmeje le ni ojileleedegberin ati mefa awon omo orile ede Naijiria ni won ti da pada sile lati orile ede Libya labe akitiyan...
Mọ si