O ti kọja 20,000 awọn aṣikiri ti o ti ku lori okun Mẹditarenia lati ọdun 2014

O ju awọn aṣikiri 20,000 ti o gbiyanju lati rekọja okun Mẹditarenia lọ si Yuroopu ti wọn ti ku lati ọdun 2014. Iku naa, eyiti a ti...
Mọ si

O koja 1,000 awọn arinrin-ajo ti o gbiyanju lati de Yuroopu lati Libiya ni ọsẹ meji akọkọ ti 2020

O ju 1,000 awọn arinrin-ajo ni o kuro ni etikun Libya ni ọsẹ meji akọkọ ti 2020 ninu igbiyanju lati de ọkọ oju omi nipasẹ Yuroopu ...
Mọ si

Arinrinajo lati Libiya kilọ fun awọn ọmọ Naijiria nipa irinajo alaibamu

Ọmọ Naijiria kan, Jubril Bukar, ti kilọ fun awọn ọmọ orilẹ-ede Naijiria ki o má lọ si irin-ajo alaibamu si Libiya. “Mo bẹ awọn ọmọ...
Mọ si

Wọn ti mu ọgọọgọrun awọn aṣikiri ni eti okun Libiya pada sinu atimọle

O to ẹẹdẹgbẹta (500) awọn aṣikiri ti o n gbiyanju lati de Ilu Yuroopu lori awọn ọkọ oju omi roba ni wọn ti mu ni eti okun Libiya l...
Mọ si

Obinrin mẹtala ku, ọmọ mẹjọ sonu lẹhin ti ọkọ oju-omi aṣikiri ti o kun ju ri nitosi Itali

Awọn olusọ eti okun Itali ti ri oku awọn aṣikiri obinrin mẹtala latinu ọkọ oju-omi ti o danu nitosi erekusu Italia ti Lampedusa ni...
Mọ si

Ijọba Libiya pe fun atilẹyin agbaye fun awọn 700,000 aṣikiri alaibamu ni Libya ni apejọ ijiroro Afirika

O to 707,000 awọn aṣikiri alaibamu ti o wa ni Ilu Libya lọwọlọwọ bayii, beni 7,000 ninu wọn wa ni ile aabo, bayii ni Oloye ti ajo ...
Mọ si

Ilu Itali: Wọn ti mu awọn ọkunrin mẹta ti n fiyaje awọn aṣikiri ninu atimole ni Libiya

Awọn ọkunrin mẹta ti wọn ti kan ni ẹsun ifipabanilopo ati ijiya awọn aṣikiri ninu atimole ilu Libiya ni awọn ọlọpa Ilu Italia ti m...
Mọ si

Rwanda yoo gba ẹẹdẹgbẹta awọn aṣikiri akọkọ ti o wa ni atimọle ni Libya

Awọn ọgọọgọrun awọn aṣikiri Afirika ni wọn yo ko kuro lati ni atimọle ni Libiya lo si Rwanda ni awọn ọsẹ to nbo. Eto yii wa lati o...
Mọ si

Ilu Eko: 153 awọn aṣikiri ọmọ Naijiria ti pada wale lati Libiya

Ni ibamu pelu awọn igbiyanju ti nlọ lọwọ lati mu awọn aṣikiri ọmọ orilẹ-ede Naijiria ti o ni idaduro ni Libya pada wa ile, ẹgbẹ ka...
Mọ si