Ọkọ igbala ti n gbe ọgọọgọrun awọn aṣikiri lati Afirika duro ni Sicily

Ni ọsẹ to kọja, ọkọ oju-omi igbala Ocean Viking, ti n gbe awọn aṣikiri 373 ni a fun ni aye iduro ni ibudo Italia ti Augusta ni Sic...
Mọ si

Italy dẹkun ọkọ igbala aṣikiri lati kuro ni ebute ọkọ oju-omi rẹ

Italy ti gbẹsẹ le ọkọ oju-omi igbala ti German-Sea Watch 3 lati mase le kuro kuro ni ebute oko naa lati tẹsiwaju awọn iṣẹ igbala a...
Mọ si

Awọn aṣikiri ti o ni iṣoro lori okun ti bọlẹ ni Italy  

Lẹhin ọpọlọpọ ọjọ lori okun Mẹditarenia, Italy ti gba ki awọn aṣikiri 180 bọlẹ si ibudo Sicili lati inu ọkọ oju-omi igbala ti Ocea...
Mọ si

Itali n gbe igbese to lẹ ni awon ibudo arinrin-ajo lehin isele coronavirus

Minisitri abe ile ni ilu Itali ti sọ fun awọn oṣiṣẹ ni awọn ibudo arinrin-ajo kakaari orilẹ-ede na lati ṣe abojuto ilera awọn arin...
Mọ si

Irin-ajo alaibamu si Yuroopu dinku si kekere julo lati ọdun 2013

Apapọ arinrin-ajo 127,657 ni o wọ Yuroopu ni ona alaibamu ni ọdun 2019, eyi ti o tunmo si pe irin-ajo alaibamu si Yuroopu wa si nọ...
Mọ si

O ju 120 arinrin-ajo ti wọn gbala ni wọn ti je ji wọn wo Itali lẹyin igba pipẹ ni ori okun

Ọkọ oju-omi nla meji gbe awọn arinrin-ajo 121 wa si awọn ebute oko oju omi meji ni Sicily, Italy, ni ọjọ kerin oṣu kejila, lẹhin i...
Mọ si

Obinrin mẹtala ku, ọmọ mẹjọ sonu lẹhin ti ọkọ oju-omi aṣikiri ti o kun ju ri nitosi Itali

Awọn olusọ eti okun Itali ti ri oku awọn aṣikiri obinrin mẹtala latinu ọkọ oju-omi ti o danu nitosi erekusu Italia ti Lampedusa ni...
Mọ si

“Iduro Irora” lori ọkọ oju-omi pari bi awọn orilẹ-ede EU mẹfa gba awọn aṣikiri ti o ni idaduro

Lehin ti wọn lo ọsẹ meji ni idaduro lori ọkọ oju-omi onigbasile ni Mẹditarenia, awọn aṣikiri ti o to 356, pẹlu awọn ọmọde ti o to ...
Mọ si

Italy se ofin titun ti o sọ awọn aṣikiri di alaini ile ati aabo

Ọpọlọpọ awọn aṣikiri ti o wa ni Italia ni wọn n le lọ si awọn oju ona lai ni aabo lẹhin ti awọn ile asofin ti fọwọsi iṣilọ tuntun ...
Mọ si