Ajọ International Organization for Migration (IOM) sọ pe awọn arinrin-ajo ti o ju 500 lọ ti ku ni igbiyanju lati kọja Mẹditarenia ...
Mọ si
O to marundinladọta awọn aṣikiri ti n lọ si Yuroopu, ni o ti ku ninu ninu jamba ọkọ oju-omi lori okun Mẹditarenia ni etikun Libya,...
Mọ si
O to 425 awọn aṣikiri ni wọn ti gba laaye lati wọ Malta lẹhin ọpọlọpọ ọsẹ ninu isoro lori okun Mẹditarenia. Awọn aṣikiri na ti o s...
Mọ si
Awọn aṣikiri 140 siwaju si wa ninu iṣoro lori okun Mẹditarenia lẹyin ti awọn alaṣẹ Maltese gba wọn kuro ninu oko oju omi ...
Mọ si
Ajo International Organisation for Migration (IOM) ti ṣe afihan ewu ti o ga fun awọn aṣikiri ti n rinrinajo lori okun Mẹditarenia ...
Mọ si
O to 150 awọn arinrin-ajo ni wọn gbala lati ni Mẹditarenia lẹhin awọn iṣẹ igbala meji otọtọ ti ọkọ oju-omi Alan Kurdi ni eti okun ...
Mọ si
O ju awọn aṣikiri 20,000 ti o gbiyanju lati rekọja okun Mẹditarenia lọ si Yuroopu ti wọn ti ku lati ọdun 2014. Iku naa, eyiti a ti...
Mọ si
Ara awọn arinrin-ajo mẹjọ ni a ri laarin wakati merinlelogun ni oṣu kejila ni eti okun Spain. Wọn wa lara arinrin-ajo to ju 1,200 ...
Mọ si
Ilọpo meji awọn aṣikiri ti oun ku lori okun Mẹditarenia ni oun ku ni ori ilẹ ki wọn to de okun na, gegebi ajo UN Refugee Agency (U...
Mọ si
12
Page 1 of 2