Wọn ti mu ọgọọgọrun awọn aṣikiri ni eti okun Libiya pada sinu atimọle

O to ẹẹdẹgbẹta (500) awọn aṣikiri ti o n gbiyanju lati de Ilu Yuroopu lori awọn ọkọ oju omi roba ni wọn ti mu ni eti okun Libiya l...
Mọ si

O koja ẹgbẹrun aṣikiri ti o ti ku sinu okun Mẹditarenia ni ọdun 2019, Ajo IOM lo sọ bee

O ti to 1,041 awọn ati asasala ti o ti ku lori awọn ọna opopona mẹta ti Mẹditarenia laarin Ojo Kini  Oṣu Kini si Ojo Keta Oṣu Kẹwa...
Mọ si

Obinrin mẹtala ku, ọmọ mẹjọ sonu lẹhin ti ọkọ oju-omi aṣikiri ti o kun ju ri nitosi Itali

Awọn olusọ eti okun Itali ti ri oku awọn aṣikiri obinrin mẹtala latinu ọkọ oju-omi ti o danu nitosi erekusu Italia ti Lampedusa ni...
Mọ si

“Iduro Irora” lori ọkọ oju-omi pari bi awọn orilẹ-ede EU mẹfa gba awọn aṣikiri ti o ni idaduro

Lehin ti wọn lo ọsẹ meji ni idaduro lori ọkọ oju-omi onigbasile ni Mẹditarenia, awọn aṣikiri ti o to 356, pẹlu awọn ọmọde ti o to ...
Mọ si

Awọn asikiri n fi emi won wewu bi ati wọ awọn orilede Europe se n nira si

Awọn isiro titun fihan pe irin-ajo lati Afirika si Yuroopu bi aṣikiri ti ko ṣe deede tẹsiwaju lati lewu pupọ. Lootọ, awọn eniyan ẹ...
Mọ si

Awon arinrinajo ti won ti ku lori okun Mediterranean ju egberun kan lo ninu abala akoko odun 2018

O le ni egberun kan awon arinrinajo ti iroyin fi mule pe won ti ta teru nipa nigba ti won n gbiyanju lati rekoja lori okun...
Mọ si