Faranse: Awọn arinrinajo wa ninu inira bi arun coronavirus se n pọsi

Ẹgbẹẹgbẹrun awọn arinrinajo ati asasala ṣin sùn si ita gbangba larin ajakaye-arun coronavirus ati titiipa ni...
Mọ si

Ọkọ oju-omi pẹlu 150 awọn arinrin-ajo ni iṣoro lori okun Mẹditarenia

O to 150 awọn arinrin-ajo ni wọn gbala lati ni Mẹditarenia lẹhin awọn iṣẹ igbala meji otọtọ ti ọkọ oju-omi...
Mọ si

Itali n gbe igbese to lẹ ni awon ibudo arinrin-ajo lehin isele coronavirus

Minisitri abe ile ni ilu Itali ti sọ fun awọn oṣiṣẹ ni awọn ibudo arinrin-ajo kakaari orilẹ-ede na lati ṣe...
Mọ si

Polandi, Hungari, ati Czech Republic le dojukọ itanran lori ẹtọ asasala

O ṣeeṣe ki orilẹ-ede Polandi, Hungari ati Czech Republic dojukọ awọn itanran ti ọle lẹhin ti ile-ẹjọ Yuroopu...
Mọ si

Laarin ikorira ati iṣọkan: Bi wọn ṣe se awọn arinrin-ajo ni Yuroopu

Lẹhin bibori awọn idiwọ nla lati de Ilu Yuroopu, ọpọlọpọ awọn arinrin-ajo  ni ireti lati ṣeto igbesi aye...
Mọ si

Grisi ya ibudó awọn arinrin-ajo sọtọ nitori arun coronavirus  

Orile-ede Grisi ti kede titiipa ibudó arinrin-ajo pẹlu awọn eniyan 2,300 lẹhin ti awọn arinrin-ajo ogún ni arun...
Mọ si

Ọpọlọpọ arinrin-ajo ti wọ Yuroopu nipasẹ okun ni ọdun yii ju ọdun 2019 lọ 

Awọn 14,854 arinrin-ajo alaibamu ati asasala ti wọ Yuroopu nipasẹ okun laarin oṣu kini si aarin oṣù keta 2020, eyii ti...
Mọ si

Bi coronavirus ṣe n kan awọn arinrin-ajo

Lati ibere rẹ ni Wuhan China, coronavirus (COVID-19) ti tan si gbogbo awọn kontineti agbaye ayafi Antarctica ati pe o ju...
Mọ si

O ti kọja 20,000 awọn aṣikiri ti o ti ku lori okun Mẹditarenia lati ọdun 2014

O ju awọn aṣikiri 20,000 ti o gbiyanju lati rekọja okun Mẹditarenia lọ si Yuroopu ti wọn ti ku lati ọdun 2014. Iku...
Mọ si