Awon arinrinajo ti won ti ku lori okun Mediterranean ju egberun kan lo ninu abala akoko odun 2018

O le ni egberun kan awon arinrinajo ti iroyin fi mule pe won ti ta teru nipa nigba ti won n gbiyanju lati rekoja lori okun...
Mọ si

Ile geesi ati Naijiria yo fowosowopo gbogun ti irinajo lona aito ati ifinisowo

Ijoba ile geesi ti so di mimo pe ohun yo kun orile ede Nigeria lowo ninu akitiyan re ninu gbigbogunti ati fi fi iya je awon...
Mọ si

Orile ede Hungari ti se ofin ti yo ma so awon oluranlowo ati agbodegba awon oluwo ti ko b’ofinmu di odaran

Ni ogunjo osu kefa odun yi, ile asofin ti orile ede olominira Hungari so awon aba kan ti yo ma so enikeni tabi ajo k’ajo to...
Mọ si

Eto ise aso riran fun awon arinrinajo obinrin ni ile ise Gucci ti ta lore ebun ebayi

Isi awon obinrin lati orile ede Nigeria ti awon kan ko wole laibofunmu wo ile Italy fun owo eru tipatipa ni won ti ri ise tuntun...
Mọ si