Bi coronavirus ṣe n kan awọn arinrin-ajo

Lati ibere rẹ ni Wuhan China, coronavirus (COVID-19) ti tan si gbogbo awọn kontineti agbaye ayafi Antarctica ati pe o ju 600,000 e...
Mọ si

O ti kọja 20,000 awọn aṣikiri ti o ti ku lori okun Mẹditarenia lati ọdun 2014

O ju awọn aṣikiri 20,000 ti o gbiyanju lati rekọja okun Mẹditarenia lọ si Yuroopu ti wọn ti ku lati ọdun 2014. Iku naa, eyiti a ti...
Mọ si

Germany kede anfani irin-ajo tuntun fun awọn arinrin-ajo onisẹ ọwọ

Germany ti kede ofin irin-ajo tuntun eyiti o gba 25,000 awọn onisẹ ọwọ wole si orilẹ-ede naa ni ọdun kọọkan, gẹgẹbi ọna lati se it...
Mọ si

Faranse fi opin si ibudo awọn arinrin-ajo ni ariwa Paris

Awọn ọlọpa Faranse ti mu awọn arinrin-ajo 427 miiran kuro ni ibudo afowohe ti o kẹhin ni ariwa ila-oorun Paris ni ọjọ Kerin Oṣu Ki...
Mọ si

Ile-ẹkọ kan ni Netherlands ngbero lati se eto irin-ajo fun awọn Naijiria ti o ni ise ọwọ

Ninu ipa lati dẹkun irin-ajo alaibamu lati Nigeria, Ile-ẹkọ Ibatan Kariaye ti Ilu Netherlands ti sọ wi pe oun ni ifẹ lati se ajọṣe...
Mọ si

O koja 1,000 awọn arinrin-ajo ti o gbiyanju lati de Yuroopu lati Libiya ni ọsẹ meji akọkọ ti 2020

O ju 1,000 awọn arinrin-ajo ni o kuro ni etikun Libya ni ọsẹ meji akọkọ ti 2020 ninu igbiyanju lati de ọkọ oju omi nipasẹ Yuroopu ...
Mọ si

Irin-ajo alaibamu si Yuroopu dinku si kekere julo lati ọdun 2013

Apapọ arinrin-ajo 127,657 ni o wọ Yuroopu ni ona alaibamu ni ọdun 2019, eyi ti o tunmo si pe irin-ajo alaibamu si Yuroopu wa si nọ...
Mọ si

O ju 120 arinrin-ajo ti wọn gbala ni wọn ti je ji wọn wo Itali lẹyin igba pipẹ ni ori okun

Ọkọ oju-omi nla meji gbe awọn arinrin-ajo 121 wa si awọn ebute oko oju omi meji ni Sicily, Italy, ni ọjọ kerin oṣu kejila, lẹhin i...
Mọ si

Arinrin-ajo mẹjọ ku sinu okun laarin wakati merinlelogun ninu igbiyanju lati de ilu Spain

Ara awọn arinrin-ajo mẹjọ ni a ri laarin wakati merinlelogun ni oṣu kejila ni eti okun Spain. Wọn wa lara arinrin-ajo to ju 1,200 ...
Mọ si