“Iduro Irora” lori ọkọ oju-omi pari bi awọn orilẹ-ede EU mẹfa gba awọn aṣikiri ti o ni idaduro

Lehin ti wọn lo ọsẹ meji ni idaduro lori ọkọ oju-omi onigbasile ni Mẹditarenia, awọn aṣikiri ti o to 356, pẹlu awọn ọmọde ti o to ...
Mọ si

Awọn asikiri n fi emi won wewu bi ati wọ awọn orilede Europe se n nira si

Awọn isiro titun fihan pe irin-ajo lati Afirika si Yuroopu bi aṣikiri ti ko ṣe deede tẹsiwaju lati lewu pupọ. Lootọ, awọn eniyan ẹ...
Mọ si

2018, Odun to le gan fun awọn aṣikiri

Awọn to n wa ibi aabo ati awọn aṣikiri ti n rii pe o nira lopolopo lati de ọdọ awọn orilẹ-ede ti o ni aabo ati ati ilọsiwaju ni 20...
Mọ si

Ijini gbe, ipọnju ati ijabọ: Irinajo buruku omo Naijiria kan

Lati igba ti ajo ton ri si iṣilọ ni agbaye (IOM) ti bere eto ipadabọ wale aalai ni pa ni May 2017, o koja awọn  7,600 aṣikiri omo ...
Mọ si

Italy se ofin titun ti o sọ awọn aṣikiri di alaini ile ati aabo

Ọpọlọpọ awọn aṣikiri ti o wa ni Italia ni wọn n le lọ si awọn oju ona lai ni aabo lẹhin ti awọn ile asofin ti fọwọsi iṣilọ tuntun ...
Mọ si

Awon agbeni rinrinajo alaibamu ni o se opolopo iwa-ipa ati ilokulo si awọn aṣikiri

Awọn agbeni rinrinajo alaibamu (smugglers) ni o ni idajọ fun ida aadọta ninu awọn iṣẹlẹ ti iwa-ipa ibalopo, iwa-ipa ti ara, jija a...
Mọ si

Germany sowopo pẹlu Nigeria lori irinajo alaibamu

Gegebi awọn ọna lati dinku oṣuwọn iṣoro ti irinajo si Europe, Germany ati Nigeria ti fi enu ko lori adehun mẹta (MoU) lati mu awọn...
Mọ si

Egbeegberun awon arinrinajo omo orile ede Nigeria ni won fi’pa mu sise asewo ni orile ede Italy

Egbeegberun awon omo orile ede Nigeria ni won fi ipa mu lati se ise asewo lodoodun ni orile ede Italy, eni ti o je adari agba fun...
Mọ si

Eto imulo ajo isokan ile alawofunfun EU: Iha wo lo ko si ile Afirika

Ajo ile alawofunfun EU ti n se akitiyan olokan o jokan lati wa ojutu kan gbogi si isoro ominlengbe awon arinrinajo ti ko...
Mọ si