Oku arabinrin omo odun mokanlelogun arinrinajo omo Nigeria ni won ti ri ni agbegbe

Gege bi ifilede ti osu karun lati odo ajo agbaye to n risi lilo lati ilu-silu (IOM), oku ariirinajo omo Naijiria na ni...
Mọ si

Egbegberun awon omo Naijiria ni won ti da pada sile lati Libya

Egberunmeje le ni ojileleedegberin ati mefa awon omo orile ede Naijiria ni won ti da pada sile lati orile ede Libya...
Mọ si

Ajo isokan ile alawo funfun EU n fe ifowosowopo to dara pelu Nigeria lori irinajo s’ile okeere

Ni ojo ayeye kan ti won fi sori “ojo ile alawofunfun ti odun 2018” to waye no abuja, asoju ajo isokan ile...
Mọ si

Awon tajode n fi’di mule pada ni Orile ede Nigeria

Egbaagbeje awon omo orile ede Nigeria ti won fi sowo pada sile lati orile ede Libya leyin ti won ti padanu ninu...
Mọ si

Germany yoo ma se idapada sile awon arinrinajo ni kiakia

Awon olopa ni ile Germany se akolu si ile awon oluwo to wa ni apa iwo oorun ilu Ellwangen ni ojo keta osu karun, iwode...
Mọ si

Egbaagbeje arinrinajo awon omo Africa ni won gbala lori okun Mẹditarenia

Awon eleto aabo oju omi to je tile Spain ti gba irinwole ni ogorin o din merin arinrinajo ni ojo kefa osu karun nigba...
Mọ si

Germany n gbero lati da egberun lona ogbon omo Nigeria arinrinajo laibofinmu pada sile

Ijoba ile Germany n gbero lakotun lati fi ogbon egberun awon omo orile ede Nigeria awolu laibofinmu sowo pada sile....
Mọ si

Akitiyan Naijiria lati dopin irinajo aibofinmu

Orile ede Naijiria ti jinle ninu wiwo ilu okere ni ona ti ko bofinmu. Ti oro ba d’oro ka wo ilu lia bikita...
Mọ si

Aadọta awọn arinrinajo omo Naijiria ti o lo Itali ni igbala

Ko kere ju awon aadọta arinrinajo omo orile-ede Naijiria ti o nlọ si orile-ede Itali ni wọn gbà ni Okun...
Mọ si