Awọn Eewu Irinajo Alaibamu fun awọn ọmọ Nigeria

Nje iwọ tabi ẹnikan ti o mọ n gbero lati rin rinajo si Europe ni ona alaibamu? Ni ọrọ miiran, se iwọ n ronu lati rinajo si Europe laisi iwe aṣẹ tabi iwe irinajo ti o tọ ati koja awọn aala ilu ni ona to dara?

Irinajo lati Nigeria si Europe ni eewu pupọ. Ni gbogbo igbesẹ irinajo na, awon arinrinajo ma n wa ni eewu ipalara, ilokulo lati ọdọ awọn agbeni rinrinajo ati awọn oniṣẹ ọdaràn.

Lati ṣe iranlọwọ fun ọ lati ṣe ipinnu ti o pe ye nipa irinajo, a ti ṣe akojọ diẹ ninu awọn eewu ti o wọpọ julọ ti awọn arinrinajo alaibamu n dojuko ni ona irin-ajo wọn.

Pe awọn amoye irinajo wa fun ododo oro nipa irinajo
Lati ọjọ Mọnday si ọjọ Friday (Ago mesan aro titi di ago merin irọlẹ)
To ba je ede Yoruba, Pidgin tabi Gẹẹsi +234 816 922 9349
To ba je ede Gẹẹsi tabi Pidgin +234 806 163 7956
O tun le lo WhatsApp ati awọn ifiranṣẹ.
Gbogbo ipe ni aabo.

Ewu ara

Awọn arinrinajo n gbiyanju lati de ilu Europe lati orilẹ-ede Nigeria ni ọpọlọpọ awọn ọna ti o lewu, bi sisa...
Mọ si

Awọn Eewu fun Awọn Obirin ati Ọmọde

Wiwọle si Europe ni eewu paapaa fun awọn obinrin ati ọmọde. Ọpọlọpọ awọn obinrin ati awọn ọmọde jiya...
Mọ si

Awọn Eewu Owo

Ṣe o n ronu iye owo ti o jẹ lati de Ilu Europe nigbati o ko ni iwe iwọlu tito? Iye owo irinajo alaibamu si Europe ko duro...
Mọ si
Pin lori